Mhideh Praise – Soji Lyrics

Soji lyrics by Mhideh Praise

Soji kuro lona iku yen
Soji kuro lona ese yen
Soji ko le ba Jesu gunwa
Tori ojo idajo ojo Idajo ti de tan

Solo
Soji o kuro lona iku re o
Ona gboro ni, ijiya ati iparun lo ja si,
To ba so ji o, wa le ba Jesu gunwa,
Tori ojo idajo ojo idajo to de tan

Chorus Soji….

Solo
Tete ronu re wo, ko kuro lona iku ni,
Ona ese yen ina ajooku lo ja si,
To ba Soji o, iye mbe fun o oo,
Igbala re o ti daju.

Chorus Soji….

Solo
To ba fe soji o, wa ko ese sile,
Waa rin ni ona pipe,
Wa oju Oluwa o, Iwo yoo si ri o,
Igbala re yoo de daju

Chorus Soji

See also: Gospel Mp3: Mhideh Praise – Soji (Prod. By JiiBStringz)

If you like this Lyrics Kindly Hesitate not to Share using the buttons below.

Leave a Reply

Meeklyrics.com.ng | Nigerian (Naija) Music Lyrics © 2017 * Sitemap